

IBUKUN OLAMIDE JOSEPH also known as HORLABOARD is one of the fast rising music minister with the ointment of grace and one of the mouth piece of God in this generation.
God is set to bless lives again through this new track titled ALARA IRE (THE WONDER DOER), this is a song that speaks about God’s undeniable act of wonders, it further reviews that when God is set to turn the table around, even the universe obeys.
download, listen to ALARA IRE (THE WONDER DOER) and be blessed.
click the below link to download the amazing song.
ALARA IRE (THE WONDER DOER) Lyrics
The lyrics sir
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Chorus…
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Verse 1…
ninu anu Re l’oti mu esteri jade
eni to w’aso eru to w’aso ofo d’aafin oba
alara ire boju wole latoke orun
ogba isele laaye lati soo d’ayaba
ona ara Re po lori’le aye koja imo wa
dafidi kekere ni olorun ara totobi gbangba
okuta eyokan pere lopa omiran to n bu ramuramu mon
baba gba isele laaye tafimi dara ire
Chorus…
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Verse 2…..
call – ona ara Re ga ah ah mo mon kos’eni toye
ona ara Re po or or mo mon ailopin ni
res – ona ara Re ga ah ah mo mon kos’eni toye
ona ara Re po or or mo mon ailopin ni
call – ona Re ga o
res – ona ara Re ga ah ah mo mon kos’eni toye
ona ara Re po or or mo mon ailopin ni
bridge….
ara loda f’eberu meta ninu ina
aye n ri ina eberu meta n ri itura
tori owo Re ni alara gbayida
ara yi mo n toro lowo alara iyanu
ara loda f’obediodomu lojosi
aye loti tan, olorun sop’osiku repete
tori owo re ni alara gbayida
je’kaye le mo pe mo ni o l’alara ire
Chorus…
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
dakun wa fimi d’ara iyanu k’araye le mo pe
Iwo l’alara ire
Oba alara ire
oba alara ire
Iwo l’oba alara ire
ara n be lowo re o to n f’aye da
bridge…
ara loda f’eberu meta ninu ina
aye n ri ina eberu meta n ri itura
tori owo Re ni bami alara gbayida
iru ara yi mo n toro lowo alara iyanu
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara toju a ri
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara t’enu yo so oo oluwa
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- aaara t’eti a gbo
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara yi, ara nla
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara ta p’enu elegan mon lori aye mi
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara ta kede mi f’araye
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara ti yo gbe ogo re yo oluwa
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara t’aye a fi mo pe moni o ni baba
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara yi ara yiiii ara ara
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu
call- ara yi ara yiiiii
res – ara yi mo n toro lowo alara iyanu