

When I sit and lay? Thinking of how in haste They want me waste… So much is the tear That my face could wear.
Even as I pray, To them I’m a prey. But then I thought about Your grace That stands so firm right in my race.
Now, I’m left alone Alone with You… As You make my life… A pattern of love with what You hewn.
I belong to You and You alone. And my song of love for You I sing…
Iwonikan SOSO.
Click the download button to download the musical video to your phone
Iwanikan soso Lyrics
IWONIKAN SOSO
Topeabiodun Omoatobijuh
Produced by PH
Iwonikan ni mo ni
Iwonikan ni mo fi fun
Okan mi ati ife mi
Iwonikan laayo mi ati ayo mi
Iwonikan soso o
Iwonikan ni mo ji fun
Iwonikan ni mo ku fun
Enibi okan mi ati ife mi
Iwonikan ni mo n wo
L’owuro, l’osan at’ale
Iwonikan soso o
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O
KO MA MA SI ENIKAN BII RE
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O O
IWONIKAN SOSO O
Iwonikan ni mo n ji ki
Iwonikan ni mo n ji ki
Iwo to femi lafetan o
Iwonikan ni mo wari fun
Mo tun juba fun
Iwonikan soso o
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O
KO MA MA SI ENIKAN BII RE
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O O
IWONIKAN SOSO O
Iwo ni ibire ati ipari
Iwo ni fitila nipa ona mi
Iwo ni owuro ati asale
Iwo ni Oluso aguntan mi oo
Ohun gbogbo lo je fun mi
Eledumare
Iwonikan soso o
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O
KO MA MA SI ENIKAN BII RE
OLOLUFE MI O
OLOLUFE MI O O
IWONIKAN SOSO O
When I think of the way
You brought me up
I can see all the love
You have for me
When I think of the care
You showed to me
I can see all the plans
You have for me
Then I sigh and I smile I sing
To the One who love me
Then I sigh and I smile I sing
Ololufe mi oo
Iwonikan soso o